FAQ

FAQ

Frequently asked question

AJASE-IPO ANTHEM

AJASE IPO ILU NLA,
LORITA LATEDOSI,
ILU OLOKIKI ILU ABINIBI MI
ODO OSIN NIWAJU,
ODO IPO LOWO EYIN
KINI UN OJE GBAGBE ILE BABA MI
ODO OYUN LOWO OKE


IBI ORIDANISI LAAGBE
AJASE IPO KONITOWO MI BAJEO
EEEEEEE MODURO TI OLUPO,
KI NKOLE MOLE MODURO TI OLUPO,
KI NSOWO KIN BODE PADE
ENIBINU AJASE, KONI FOJU BA OSIN
EYAN TIO FE TOLUPO,
KONI DELE IPO KAPAWOPO
GBELARUGE, KAPAWOPO
GBELARUGE OHUN ANI LAAAGBE
OHUN ANI LAAGBE LARUGE
KI OLUWA KO’RAN WA LOWO